ITANKALE AWON OMO YORUBA

YORUBA LANGUAGE
JSS1
OSE KINNI
ITANKALE AWON OMO YORUBA
Awon Omo omo Odudua wonyi fi ile Ife ti o je orirun won sile lo tedo si awon ilu wonyi
Omo Odudua Ilu ti won tedo si Orile Ede
Olowu Owu Naijiria
Alaketu Ketu Naijiria
Oba Ibini Bini Naijiria
Orogun Ila Naijiria
Onisabe Sabee Orile olominira Bini
Olupopo Popo Orile olominira Bini
Oranmiyan Oyo Naijiria

Nitori Oro ija Aala Ile tabi Oye Idile, Opo Omo tabi molebi Odudua fi ile ife sile. Awon Oba Alade Merindinlogun Ile Ekiti lo te Ilu ti won do. Awon Oba Alade wonyi tedo si ilu yi.
Oruko won Ilu ti won lo tedo si
Osemawe Ondo
Ebumawe Ago Iwoye
Ogborogan Ijebu Ode
Akarigbo Remo
Olowo Owo
Oloja Ikale/Ilaje
Jegun Ile Oluji
Atewogbeja Osogbo
Owa Ajaka Ijesa

Awon Ipinle ti Iran Yoruba Wa ni Naijiria

  1. Ipinle Oyo
  2. Ipinle Osun
  3. Ipinle Ogun
  4. Ipinle Ondo
  5. Ipinle Ekiti
  6. Ipinle Eko
  7. Apa kan Ipinle Kuwara
  8. Apa Kan Ipinle Kogi
  9. Apa Kan Ipinle Edo

Ise Sise
Ni Iwo Oorun Naijiria, So awon ipinle Marun-un ti a ti le ri Omo Yoruba.