Aroko pipa ni ode-oni

AROKO NI ODE-ONI
Aroko igbalode po kaakiri egbee titi ti won n dari awako bi o se gbodo was oko re. Apeere won ni:
1.Ina monamona adari oko( ???? )———Awo meta ati itumo won fun awako niyii
Awo pupa: Pe ki oko duro
Awo ofeefee(yellow): Gbaradi lati si tabi duro
Awo ewe(green): ki oko maa lo

 1. Isoda elese(zebra crossing) —— duro fun elese lati soda
 2. Patako Ajuwe ona➡️——- ya si otun
 3. Ibi to ni ewu☠️——— nkan to lewu wa ni bi.
  5.Leta Kiko ati waya Tite——- Fifi ero inu eni ranse si enikeji
 4. Asia Orile-ede (????????)——-Aroko ni asia pa. Itumo re:
  Awo ewe: ise agbe
  Awo funfun: alaafia.
 5. Ami ijoba orile ede( coat of arms)——- Aroko ni aworan yii pa. Itumo won: Esin meji ati eye asa tumo si Agbara
  Odo oya/ Odo Benue tumosi isokan.
  Esin Oro(Motto): Isokan ati ireti, Alaafia ati Ilosiwaju
  Ere agba meta ti o wa ni ilu eko—— Itumo ere wonyi ni pe ki a ja fafa ni ilu eko. Itumo okookan ni pe:
 6. Oo gbodo suegbe
 7. Oo gbodo nagere
 8. Oo gbodo ya mugu.