Atunyewo Mofiimu Ede Yoruba.
Mofiimu ni ege ti o kere julo ti o si ni itumo ati ise ti o n se ninu girama ede .
Ona meji Pataki ti mofiimu pin si ni:
1) Mofiimu adaduro ati
2) Mofiimu afarahe.
Mofiimu ko see fo si wewe mo ki o tun ni itumo. Apeere: bi a ba se ayipada si awon mofiimu bii: omo, epo ai, abbl, ko le ni itumo mo.
Eya mofiimu:
Orisi meji ni:i) Mofiimu ipile/adaduro
ii) Mofiimu afarahe (afomo)
3) Mofiimu lpile/Adaduro: O je fonran/ege ti o le daduro laije pe a lot mofiimu miiran mo. Apeere: Aja, omi, iwe, ori, okan, ese abbl.
i) O le je oro-oruko bii; omi,iyan, adiye abbl. Irufe oro-oruko yii kii ni afomo, won kii si se Oro iseda.
ii) Oro-apejuwe; die, rere, nla abbl
iii) Oro-aponle: rokoso, jaujau, banba abbl.
iv) Oro-ise; lo, jeun, sun, ku, rin abbl.
2) MOFIIMU AFARAHE:
Mofiimu afarahe ko le da duro. A maa n lo papo mo mofiimu adaduro ni lati fi kun itumo iru mofiimu adaduro bee.
A pin mofiimu afarahe si Ona meta bayii;
i) afomo ibere (iwaju)
ii) afomo aarin ati
iii) afomo eyin.
Mofiimu lpile/Adaduro ni a maa n fi afomo ibere wonyi kun ki o le ni itumo. Apeere;
Afomo ibere—Oro-ise—Oro ti a seda.
a + yo = ayo
i + fe = ife
o + selu = oselu
ai + sun = aisun
on + de = onde
ati + sun = atisun
e + ko = eko
o + mu = omu
e + to = eto
APEERE MOFIIMU AARIN;
omo+ki+ omo = omokomo
Ile+ ki+ ile = ilekile
oju+ kan+ oju = ojukanju