AWON OBA ALADE NI ILE YORUBA

YORUBA LANGUAGE
JSS1
OSE KEJI
AWON OBA ALADE NI ILE YORUBA
Oruko Oye Ilu
Ooni Ile Ife
Alaafin Oyo
AtaOja Osogbo
Awujale Ijebu-Ode
Akarigbo Ijebu Remo
Ayangbunren Ikorodu
Alaye Odoogbolu
Afinbiokin Ijebu-Jesa
Alanii Ido-Ani
Ajero Ijero
Ajalorun Ijebu-Ife
Akire Ikire
Abodi Ikoya
Alaketu Ketu
Alamuwa Ado-Odo
Alaye Ayetoro(Yewa)
Aseyin Iseyin
Apetumodu Ipetumodu
Olowo Owo
Deji Akure
Dagburewe Idowa
Ewi Ado-Ekiti
Elekoo Eko
Elekole Ikole
Gbagura Agura
Olu Ilaroo
Ogiyan Ejigbo
Oluwoo Iwo
Osemawe Ondo
Olubadan Ibadan
Olowu Owu
Onisabe Sabe
Oore Otun Ekiti
Orimolusi Ijebu Igbo
Onimala Imala
Olubara Ibara
Olugbon Ile Igbon
Olomu Omu-Aran
Olufi Gbogan
Ogoga Ikere
Okere Saki
Odemo Isara
Oba Akaran Badagry
Oore Otun Ekiti
Olupo Ajase-Ipo
Olofa Ofa
Saki Arigidi
Timi Ede
Owaoye Oke Imesi

Ise Sise
So Oruko Oye awon Oba Ilu wonyi

  1. Oyo
  2. Ibadan
  3. Ede
  4. Osogbo
  5. Ijebu Jesa