Didekun iwa ika si Omolakeji

DIDEKUN IWA IKA IKA SI OMOLAKEJI
Iwa ika ni iwa ibi, iwa buburu ti omo eniyan n hu si omolakeji ni aye. Bi iwa ika se wa ni aye atijo naa ni o wa lode-oni. Iwa ika you pin si orisirisi.
IWA IKA TI O WOPO NI AYE ATIJO
1) Ikonileru
2) Ifinisofa
3) Fifi eniyan rubo
4) Gbigbe ese le iyawo-oniyawo
5) Like obinrin ni mogun/magun
6) Ami idanimo ni oju eru.
IWA IKA TI O WOPO LODE-ONI
i. Jijinigbe
ii. Ipaniyan
iii. Lilo omo nilo-kulo
iv. Lilu iyawo ile
v. Ifomosowo
vi. Ifipa-ba-obinrin-lo
vii. Lilu omo ni ilukilu
viii. Biba omode ni asepo
ix. Titan Arun kale ni ona aito.
ONA DIDEKUN IWA IKA NI AWUJO
i. Gbigba alaafia laaye nigba gbogbo.
ii. Fifi agbofinro mu awon aseka ni awujo
iii. Fifi ara eni si ipo omolakeji ti a ba few se ohun ika.
iv. Siso ibinu olorun Lori asebi fun won boya won le yi pada
v. Fifi iya to to labe ofin je eni ti o ba huwa ika, ki o le je arikogbon fun elomiran.
ISE SISE
I. Menu ba iwa ika meta ti o wopo no aye atijo, ki o si se alaye soki Lori won.