Ede Yoruba 1

3rd week
SS3, 2019/2020
Dahun gbogbo awon ibeere wonyi.
Fa awe Gbolohun afarahe ti o wa ninu okookan awon Gbolohun wonyi yo; ki o si so iru awe Gbolohun afarahe ti o je.
(1) Maa gbowo ti o je mi
(2) Bi o ba few o le pe mi
(3) O ya m ok lenu pe Olu wa.
(4) Maa feyawo ki n to ra Moto.
(5) Lara to a n soro re ti de.
(6) kaka ki n jale maa kuku deru.
(2) Se Apejuwe awon Oro -aropo-oruko ati afarajoruko to o wa ninu okookan awon Gbolohun wonyi.
(1) Eyin wo ni e n pariwo yen?.
(2) Won kii gbonran boro
(3) Emi ti gba a.
(4) Awa ni oriire kan.
(5) Oun gan an Ni mo fun in
(6) Awa ti gbo
(3) Ko awon Oro wonyi ni ilana adako foniimu.
(a) efon
(b) opolo
(d) ojogbon
(e) sugbon
(e) Eyin
(f) okunrin
(g) diedie
(4) Kin ni mofiimu?
(b) Pin okookan awon Oro wonyi si mofiimu.
(1) idaro (2) omuti (3) ilegbee (4) eranko (5) ailowolowo (6) onkowe (7) omokomo (8) pejapeja (9) ontaja (10) omodekunrin
(5) Toka si iru Gbolohun to okookan awon wonyi je.
(1) Bola ni o pa aja naa
(2) Nje e to jeun?
(3) E jokoo.
(4) O nise amo ko lowo.
(5) Aja gbo.
(6) Tumo akanlo ede wonyi.
(1) fori oka homu.
(2) ta teru nipaa.
(3) gun igi koja ewe
(4) ru eti omolangidi
(5) na Papa bora

(6) fi enu Oro jona
(7) Se Apejuwe awon iro konsonanti wonyi.
h, j, g, t, p, f, r, d, n, b