Ede Yoruba 1


(1) Toka si orisi Gbolohun to awon Gbolohun wonyi je.
(1) Bi a ba wa a ko ni sun.
(2) Aja n gbo
(3) O lowo amo ko ko kole
(4)Ro mi ro re
(5) Olu ka aso wole
(6) Kani mo lowo maa ko le
(7 ) Olu koi tii to ra aso odun
(8) Bola ni o ra bata
(9) A ri won
(10) Won r a omi mu
(2) So itumo awon oruko Yoruba wonyi
(1) Ajayi (2) Ojo (3) Aina (4) Olugbodi (5) Dada (6) Oke (7) Ige (8) Amusan (8) Ilori (9) Aja (10) Odu
(3) Pin awon Oro wonyi si silebu nipa lilo batani KF KF
(1) Binbo (2) Lola (3) Olopaa (4) Motunde (5) Odaran
(4) Fala si abe awe Gbolohun afarahe to wa ninu awon Gbolohun wonyi.
(1) Won to pari ise ki n to de
(2) Osan ti mo mu ko pon.
(3) O ra bata lati tun ta
(4) Mo ranti pe n ko ti i jeun
(5) Ogede to baba ra to bake
(6) Pe won tete de ya mi lenu
(7) Ile to mo ko tobi
(8) Iroyin pe oga de ti tan kale
(9) Omo to baba na ti salo
(10) A ko ni sun bi a ba wa.