Idanrawo

           IDANRAWO

1) Bawo ni a se ko ogbomosho ni akoto ode -oni?
2) Ilana wo ni a fi n ko niwonigbati?
3) Konsonanti afeyinfetepe ni————
4) Ona meloo ni Oro ayalo pin si?
5) Iro ti a paje ninu eebu ni———
6) Iro ohun ti o ye fun ‘bata’ ( a kind of drum) ni ————
7) Bi a ti n sipeli pepeiye ni ————
8) Aadoje je?
9) Kin ni 305?
10) Figo fun Eedegbefa ni————
11) Oro oruko oluwa ti o wa ninu Adekunle ti o lo Akure ra moto
12) Iwa buruku ko ye omo eniyan. Buruku inu gbolohun yii je?
13) O gbe igi naa pelebe. Isori oro wo ni naa
14) Won ti gba isinmi. Won inu gbolohun yii je?
15) Ata naa pon wee. Wee Oro ———-
16) Meloo ni iro konsonanti afeji-ete-pe?
17) Bawo ni a se le ko alanu ni ilana akoto ode oni?
18) Apapo iro faweli je meloo?
19) Iwo pelu kola ni e lo. Oro asopo inu gbolohun yii ni———
20) Ewi alohun wo lo wopo ni agbegbe Ondo?
21) Awon wo ni Yoruba n ki ni Arepon aredu o?
22) Idile wo ni o n je Ojediran
23) Ewo ni a fin se adura ogbo fun omo tuntun?
24) Bawo ni a se n pe apeja oba Egba?
25) Ounje wo ni a mo mo awon ijebu
26) Awon wo lo ni dadakuada?
27) Awon osise wo ni a n ki ni Ojugbooro ooo
28) Ta ni o koko fi ede Yoruba waasu ni ile saro?
29) Tani o te ilu oyo do?
30) Ki ni oruko ti awon oyinbo koko n pe awon Yoruba ni ile Saro?
31) Bawo ni Oranmiyan se di eni to loroo ju awon egbon re to ku lo? Nipa —––———–
32) Ki ni o faa ti Oduduwa fi kiro ni ilu Meka?
33) ————- ni Oduduwa ba ni Ile-Ife
34) Ewo ni o jogun Ileke?
35) Ijo wo ni o se agbateru Kiko ede Yoruba sile?
36) Konsonanti aranmupe asesilebu ni?
37) Langbe ori ebe ————- ni a n polowo bayi
38) Gbigbe oja si oju kan fun onibaara lati ra ni?
39) Pari ipolowo yii “dodo———- re e o
40) 4000 ni onka Yoruba ni?
IPIN B
1) Ko awon onka wonyi ni figo
i. Ookanlelegberin
ii. Okoo
iii. Otalelegbawaa
iv. Eedegbaaji
v. Orin-le-le-gberin
2) Ko awon Oro wonyi ni sipeli ode oni
i. Nigbati
ii. Olopa
iii. Aiye
iv. Biotilejepe
v. Lehinti
vi. Ibiti
vii. Ewoni
viii. Nigbagbogbo
ix. Oni opa
x. Ko eko
3) Daruko agbegbe ti a ti n lo awon ewi alohun wonyi
i. Obitun
ii. Bolojo
iii. Rara
iv. Ekun iyawo
v. Olele
vi. Apepe
vii. Orin Etiyeri
viii. Biripo
ix. Igbala
x. Adamo
4) Menu ba ona iranra- eni-lowo marun-un