Idanwo ranpe

Dahun awon ibeere wonyi:

 1. Inu aroko wo ni a ti maa n ri ipede yii: se alaafia ni e wa.
 2. Adireesi meloo ni leta aigbefe maa n ni?
  3.Ibi ti adireesi agbaleta maa n wa ninu leta aigbefe ni———
  4.Aroko wo lo maa n sotun sosi ?
 3. Ami yii (/)duro fun Am bii ——— ninu ede Yoruba.
  6.silebu meloo lo wa ninu ALANGBA?
  7.Fifi kaninkanin ranse si eniyan gege bi aroko tumo si———
  8.Odun wo ni ede Yoruba do kiko sile?
 4. 300 ni a n pe ni ——- ni onka Yoruba
  10.395 je ———-
  Ilu wo ni a ti koko ko ede Yoruba sile?
 5. Mo ri Ade ni oja. Mo je isori oro wo?
  Iya Yemi to de lati Eko. De je oro——–
  12.Ewure ti a so mole ti salo? Iru gbolohun wo niyi?
 6. Sola jokoo. Jokoo je oro——–
 7. Oro —— ni opomulero ninu gbolohun.
  15.Ile na mo tonitoni. tonitoni je oro——–
 8. Awon —— lo ni ijala
 9. Tani abikeyin omo okanbi?
 10. Oruko oye oba ilu Ilesa ni———
 11. Eya Yoruba wo lo n pe isu ni usu
 12. Ewo ni o korira adi ninu awon orisa ile Yoruba?
  IPIN B
 13. Menuba ohun marun ti o le fa ki obinrin ya agan
  2 ki ni itumo awon Aroko wonyi:
  a. Akisa aso
  b.Ewe tutu
  d.Awe obi
  e. Awo Ehoro
  e.Irosun
 14. Kin ni oruko oba ilu wonyi:
  a.Ondo
  b.Remo
  d.osogbo
  e.Ago – Iwoye
  e. Ijesa.
 15. So isori oro ti a ko yato ninu awon gbolohun won yi:
 16. Aso funfun ni iyawo wo
 17. Femi rerin-in
 18. Oun lo fa aso mi ya
 19. Mo* ra iwe
  5.Wa ri mi ni ola
 20. Menuba ona isenupe awon iro wonyii:
  1./w/
  2./s/
  3./b/
  4./t/
  5./k/
 21. Send your answers to this number on WhatsApp 07063957411 by 8am tomorrow.