ORO APEJUWE

J SS2 ( Note)
ISORI ORO ( Part of speech)
ORO APEJUWE
Eyi ni Oro ti o n se atenumo fun Oro oruko. Apeere,
(I) Moto kekere ni oga ra.
( ii) Omo radarada kii se omo.
(iii) Omo pupa gba ebun.
((iv) lle nla po ni Abuja.
(2) ORO APONLE
Eyi ni Oro ti o n se atenumo fun Oro ise. Apeere:
(I) lbon Ode dun .gbau.
(ii) Giloobu naa mole rokoso
(iii) Bola n jeun waduwadu.
(iv) Olu n rin kemokemo.
(3) ORO ATOKUN (preposition)
Meta ni awon Oro atokun wonyi.
Oun ni oro ti o n toka ajumose laaarin oro oruko ati Oro ise. Awon ni: ni, si, ti. Apeere:
(I) Wa ri mi ni Eko
(ii) Bolu wa si lbadan
(iii) Ope ti lo si Abuja
(iv) Olu ti Eko ja si Abuja.
(4) ORO-ISE
Oro ise ni opomulero ninu gbolohun. Koseemani ni, oun lo n so ohun so nipa isele tabi ohun to sele si enikan ninu gbolohun. Apeere:
(I) Olu ri Mi
(ii) Won pa eran
(iii) Bola ra isu je.
(iv) O ti sun
(5) ORO ORUKO
Eyi ni awon Oro ti o ma a n sise Oluwa, abo, ati eyan ninu gbolohun.
Apeere:
(1) (a) Oluwa: Lara sun
(b) Olu n korin
(d) Tade jeun
(2) Abo: (I) Won ri ejo
(ii) Baba Bola wo bata pupa
(iii) Ode pa aja
(3) Eyan: (I) Aso Ode ni Olu wo
(ii) lya Dele wo ewu aranl
(iii) Olu pa eye tin-in tin-in